T. A. Bankole-Oki

T. A. Bankole-Oki

Alakoso Idajo Ipinle Eko
In office
1967–1975
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1919-11-15)15 Oṣù Kọkànlá 1919
Aláìsí13 August 2010(2010-08-13) (ọmọ ọdún 90)

Tanimose Abioye Bankole-Oki (November 15, 1919 - August 13, 2010) je agbejoro ara Naijiria to di Agbẹjọ́rò Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà ni ojo 12 osu kinni 1978. Bankole-Oki lo je alakoso idajo ni Ipinle Eko lati 1967 titi de 1975.



Itokasi

Prefix: a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9

Portal di Ensiklopedia Dunia

Kembali kehalaman sebelumnya